Numbers 15:35
35
Nígbà náà ni
Olúwa
sọ fún Mose pé, “Kíkú ni ọkùnrin náà yóò kú kí gbogbo ìjọ ènìyàn Israẹli sọ ọ́ lókùúta pa ní ẹ̀yìn ibùdó.”
Copyright information for
YorBMYO